歌词

Ololufe wo oju mi
So fun mi p'oo fe mi
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa
Ololufe wo oju mi
So fun mi p'oo fe mi
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O wa fi idanu si'nu wa
Lati mo 'fe, lati mo ore
O fi idanu si'nu wa
Lati mo 'fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa
Ayo wa ti d'ajose
Ola wa ti d'ajoni
Irin wa ti d'ajorin
Ibanuje ko jina si wa
Wo mi o tun mi wo pel'oju inu
Irin wa laye jo'ra won
Wo mi o tun mi wo pel'oju inu
Irin wa laye jo'ra won
Ayanmo wa j'ayanmo
Loro ife wa se se regi
Ayanmo wa jo ayanmo
Loro ife wa se se regi
Owo mi ree o fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa
Ko le se ki ija ma wa
Jowo je a jo s'asoye
B'oro ba se bi oro
Jowo fi suuru ba mi se
Ore okan mi pe mi o bi mi
Ogiri wa ko ma a la'nu
Ore okan mi pe mi o bi mi
Ogiri wa ko ma a la'nu
B'aa ba f'imo wa s'okan
Oke oke la o ma lo
B'aa ba f'imo wa s'okan
Oke oke la o ma lo
Owo mi ree yi o fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa
Ololufe wo oju mi
So fun mi p'oo fe mi
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa
Ololufe wo oju mi
So fun mi p'oo fe mi
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O wa fi idanu si'nu wa
Lati mo 'fe, lati mo ore
O fi idanu si'nu wa
Lati mo 'fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa
B'afefe idanwo ba fe de
Duro ti mi o girigiri
B'o ti wu k'oorun mu to
Sanmo dudu a wa dandan ni
B'afefe idanwo ba fe de
Duro ti mi o girigiri
B'o ti wu k'oorun mu to
Sanmo dudu a wa dandan ni
Iwenumo ma lo je, ka tun le r'aanu gba si ni
Isoro oni adun ola ni, ayo at'ope lo ma ja si
Owo mi ree yi o fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O wa fi idanu si'nu wa
Lati mo 'fe, lati mo ore
O fi idanu si'nu wa
Lati mo 'fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O wa fi idanu si'nu wa
Lati mo 'fe, lati mo ore
O fi idanu si'nu wa
Lati mo 'fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O f'imole re fun mi
O f'agbara mi fun o
O wa fi idanu si'nu wa
Lati mo 'fe, lati mo ore
O fi idanu si'nu wa
Lati mo 'fe, lati mo ore
Owo mi ree, fa mi dani
Ase Oluwa ni
Ayanmo ife la je fun 'ra wa
Lat'odo Eni to da wa

Writer(s): Olusola Allyson-obaniyi, Tolu Fafowora

不想看到广告?马上升级

API Calls

从 Spotify 记录音乐?

将您的 Spotify 帐户连接到您的 Last.fm 帐户,通过任何设备或平台上的任何 Spotify 应用记录您所听的一切内容。

连接到 Spotify

关闭